Online Bible

- Reklamy -




Heberu 1:11 - Yoruba Bible

11 Wọn óo parẹ́ ṣugbọn ìwọ óo wà títí. Gbogbo wọn óo gbó bí aṣọ.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

11 Nwọn ó ṣegbe; ṣugbọn iwọ ó wà sibẹ, gbogbo wọn ni yio si gbó bi ẹwu;

Viz kapitola kopírovat

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

11 Wọn yóò ṣègbé, ṣùgbọ́n ìwọ yóò wà síbẹ̀ gbogbo wọn ni yóò di àkísà bí ẹ̀wù.

Viz kapitola kopírovat




Heberu 1:11

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy