Filemoni 1:4 - Yoruba Bible4 Nígbà gbogbo tí mo bá ń ranti rẹ ninu adura ni mò ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun. Viz kapitolaBibeli Mimọ4 Emi ndupẹ lọwọ Ọlọrun mi nigbagbogbo, emi nṣe iranti rẹ ninu adura mi, Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní4 Èmi máa ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run nígbà tí mo bá rántí rẹ nínú àdúrà mi, Viz kapitola |