Online Bible

- Reklamy -




Eksodu 1:15 - Yoruba Bible

15 Nígbà tí ó yá, ọba Ijipti pe àwọn obinrin Heberu tí wọ́n ń gbẹ̀bí, tí orúkọ wọn ń jẹ́ Ṣifira ati Pua, ó sọ fún wọn pé,

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

15 Ọba Egipti si wi fun awọn iyãgbà Heberu; orukọ ọkan ninu ẹniti ijẹ Ṣifra, ati orukọ ekeji ni Pua:

Viz kapitola kopírovat

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

15 Ọba Ejibiti sọ fún àwọn agbẹ̀bí Heberu ti orúkọ wọn ń jẹ́ Ṣifura àti Pua pé:

Viz kapitola kopírovat




Eksodu 1:15

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy