Daniẹli 1:6 - Yoruba Bible6 Daniẹli, ati Hananaya, ati Miṣaeli ati Asaraya wà lára àwọn tí wọ́n ṣà ninu ẹ̀yà Juda. Viz kapitolaBibeli Mimọ6 Njẹ ninu awọn wọnyi ni Danieli, Hananiah, Miṣaeli, ati Asariah, lati inu awọn ọmọ Juda: Viz kapitolaBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní6 Lára àwọn wọ̀nyí ni àwọn tó wá láti Juda: Daniẹli, Hananiah, Miṣaeli àti Asariah. Viz kapitola |