Online Bible

- Reklamy -




Sefaniah 1:4 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

4 “Èmi yóò na ọwọ́ mi sórí Juda àti sórí gbogbo àwọn ènìyàn tí ń gbé ní Jerusalẹmu. Èmi yóò sì ké kúrò níhìn-ín-yìí ìyókù àwọn Baali, àti orúkọ àwọn abọ̀rìṣà pẹ̀lú àwọn àlùfáà abọ̀rìṣà,

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

4 “N óo na ọwọ́ ibinu mi sí ilẹ̀ Juda, ati sí àwọn tí ń gbé Jerusalẹmu. N óo pa gbogbo oriṣa Baali tí ó kù níhìn-ín run, ati gbogbo àwọn babalóòṣà wọn;

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

4 Emi o nà ọwọ́ mi pẹlu sori Juda, ati sori gbogbo ara Jerusalemu; emi o si ké iyokù Baali kuro nihinyi, ati orukọ Kemarimu pẹlu awọn alufa;

Viz kapitola kopírovat




Sefaniah 1:4

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy