Online Bible

- Reklamy -




Sefaniah 1:3 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

3 “Èmi yóò mú ènìyàn àti ẹranko kúrò; èmi yóò mú àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run kúrò àti ẹja inú Òkun, àti ohun ìdìgbòlù pẹ̀lú àwọn ènìyàn búburú; èmi yóò ké ènìyàn kúrò lórí ilẹ̀ ayé,” ni Olúwa wí.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

3 ati eniyan ati ẹranko, ati gbogbo ẹyẹ, ati gbogbo ẹja. N óo bi àwọn eniyan burúkú ṣubú; n óo pa eniyan run lórí ilẹ̀.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

3 Emi o mu enia ati ẹranko kuro; emi o mu ẹiyẹ oju ọrun kuro, ati ẹja inu okun, ati ohun idigbòlu pẹlu awọn enia buburu; emi o si ké enia kuro lori ilẹ, ni Oluwa wi.

Viz kapitola kopírovat




Sefaniah 1:3

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy