Online Bible

- Reklamy -




Ọbadiah 1:9 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

9 A ó ṣe ẹ̀rù ba àwọn jagunjagun rẹ, Ìwọ Temani, gbogbo àwọn tó wà ní orí òkè Esau ní a ó gé kúrò nínú ìpànìyàn náà.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

9 Ìwọ ìlú Temani, ìbẹ̀rùbojo yóo dé bá àwọn akọni rẹ, gbogbo àwọn ọkunrin tí wọ́n wà ní òkè Esau ni a óo sì fi idà pa.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

9 Awọn alagbara rẹ yio si bẹ̀ru, iwọ Temani, nitori ki a le ke olukuluku ti ori oke Esau kuro nitori ipania.

Viz kapitola kopírovat




Ọbadiah 1:9

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy