Ọbadiah 1:8 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní8 Olúwa wí pé, “Ní ọjọ́ náà, Èmi kì yóò ha pa àwọn ọlọ́gbọ́n Edomu run, àti àwọn amòye run kúrò ní òkè Esau? Viz kapitolaYoruba Bible8 “Ní ọjọ́ náà, ni n óo pa àwọn ọlọ́gbọ́n run ní Edomu, òye wọn yóo sì di òfo ní òkè Esau. Viz kapitolaBibeli Mimọ8 Oluwa wipe, li ọjọ na ki emi o run awọn ọlọgbọn kuro ni Edomu, ati imoye kuro li oke Esau? Viz kapitola |