Ọbadiah 1:6 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní6 Báwo ni a ṣe ṣe àwárí nǹkan Esau, tí a sì wá ohun ìní ìkọ̀kọ̀ rẹ̀ jáde. Viz kapitolaYoruba Bible6 Ogun ti kó Esau, gbogbo ìṣúra rẹ̀ ni wọ́n ti kó tán! Viz kapitolaBibeli Mimọ6 Bawo li a ti ṣawari awọn nkan Esau! bawo li a ti wá awọn ohun ikọkọ rẹ̀ jade! Viz kapitola |