Online Bible

- Reklamy -




Ọbadiah 1:20 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

20 Àwọn ìgbèkùn Israẹli tí ó wà ní Kenaani yóò ni ilẹ̀ títí dé Sarefati; àwọn ìgbèkùn láti Jerusalẹmu tí ó wà ní Sefaredi yóò ni àwọn ìlú gúúsù ní ìní

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

20 Àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n wà ní oko ẹrú ní ilẹ̀ Hala wọ́n óo gba ilẹ̀ Fonike títí dé Sarefati; àwọn eniyan Jerusalẹmu tí wọ́n wà ní oko ẹrú ní ilẹ̀ Sefaradi yóo gba àwọn ìlú tí ó wà ní Nẹgẹbu.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

20 Ati igbèkun ogun yi, ti awọn ọmọ Israeli ti o wà larin awọn ara Kenaani, titi de Sarefati; ati igbèkun Jerusalemu ti o wà ni Sefaradi, yio ni awọn ilu nla gusu.

Viz kapitola kopírovat




Ọbadiah 1:20

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy