Online Bible

- Reklamy -




Ọbadiah 1:18 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

18 Ilé Jakọbu yóò sì jẹ́ iná àti ilé Josẹfu ọwọ́ iná ilé Esau yóò jẹ àgékù koríko wọn yóò fi iná sí i, wọn yóò jo run. Kì yóò sí ẹni tí yóò kù ní ilé Esau.” Nítorí Olúwa ti sọ̀rọ̀.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

18 Ilé Jakọbu yóo dàbí iná, ilé Josẹfu yóo dàbí ọ̀wọ́ iná, ilé Esau yóo sì dàbí àgékù koríko. Wọn yóo jó ilé Esau; àwọn ìran Esau yóo jó àjórun láìku ẹnìkan; nítorí pé OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

18 Ile Jakobu yio si jẹ iná, ati ile Josefu ọwọ́-iná, ati ile Esau fun akeku-koriko, nwọn o si ràn ninu wọn, nwọn o si run wọn; kì yio si sí ẹniti yio kù ni ile Esau: nitori Oluwa ti wi i.

Viz kapitola kopírovat




Ọbadiah 1:18

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy