Ọbadiah 1:13 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní13 Ìwọ kì bá tí wọ inú ibodè àwọn ènìyàn mi lọ, ní ọjọ́ àjálù wọn. Ìwọ kì bá tí fojú kó wọn mọ́lẹ̀ nínú ìdààmú wọn, ní ọjọ́ àjálù wọn. Ìwọ kì bá tí jí ẹrù wọn kó, ní ọjọ́ ìpọ́njú wọn. Viz kapitolaYoruba Bible13 O kì bá tí wọ ìlú àwọn eniyan mi ní ọjọ́ ìpọ́njú wọn; o kì bá tí fi wọ́n ṣẹ̀sín ní ọjọ́ àjálù wọn; o kì bá tí kó wọn lẹ́rù ní ọjọ́ ìpọ́njú wọn. Viz kapitolaBibeli Mimọ13 Iwọ kì ba ti wọ inu ibode awọn enia mi lọ li ọjọ idãmú wọn; nitotọ, iwọ kì ba ti ṣiju wo ipọnju wọn li ọjọ idãmú wọn, bẹ̃ni iwọ kì ba ti gbe ọwọ́ le ohun ini wọn li ọ̀jọ idãmú wọn. Viz kapitola |