Ọbadiah 1:11 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní11 Ní ọjọ́ tí ìwọ dúró ní apá kan, ní ọjọ́ tí àlejò kó ogún rẹ lọ, tí àwọn àjèjì sì wọ ibodè rẹ tí wọ́n sì sẹ́ kèké lórí Jerusalẹmu, ìwọ náà wà bí ọ̀kan nínú wọn. Viz kapitolaYoruba Bible11 Ní ọjọ́ tí àwọn ọ̀tá ń kó ọrọ̀ wọn lọ, tí àwọn àjèjì wọ inú ìlú wọn, tí àwọn ọ̀tá sì ń ṣẹ́ gègé lórí Jerusalẹmu, ẹ dúró, ẹ̀ ń wò wọ́n; ẹ sì dàbí ọ̀kan ninu wọn. Viz kapitolaBibeli Mimọ11 Ni ọjọ ti iwọ duro li apa keji, ni ọjọ ti awọn alejo kó awọn ogun rẹ̀ ni igbèkun lọ, ti awọn ajeji si wọ inu ibode rẹ̀, ti nwọn si ṣẹ keké lori Jerusalemu, ani iwọ wà bi ọkan ninu wọn. Viz kapitola |