Online Bible

- Reklamy -




Ọbadiah 1:10 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

10 Nítorí ìwà ipá sí Jakọbu arákùnrin rẹ, ìtìjú yóò bò ọ, a ó sì pa ọ run títí láé.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

10 “Nítorí ìwà ìkà tí ẹ hù sí àwọn ọmọ Israẹli, arakunrin yín, ojú yóo tì yín a óo sì pa yín run títí lae.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

10 Nitori ìwa-ipa si Jakobu arakunrin rẹ itiju yio bò ọ, a o si ke ọ kuro titi lai.

Viz kapitola kopírovat




Ọbadiah 1:10

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy