Online Bible

- Reklamy -




Numeri 1:34 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

34 Láti ìran Manase: Gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ogún ọdún sókè, tí wọ́n lè lọ sójú ogun ni wọ́n to orúkọ wọn lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ẹbí àti ìdílé wọn.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

34 Ninu ẹ̀yà Manase, àwọn tí wọ́n tó ẹni ogún ọdún, tí wọ́n tó lọ sójú ogun, gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn ní ìdílé-ìdílé

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

34 Ti awọn ọmọ Manasse, iran wọn, nipa idile wọn, nipa ile baba wọn, gẹgẹ bi iye orukọ, lati ẹni ogún ọdún lọ ati jù bẹ̃ lọ, gbogbo awọn ti o le jade lọ si ogun;

Viz kapitola kopírovat




Numeri 1:34

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy