Nehemiah 1:1 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní1 Ọ̀rọ̀ Nehemiah ọmọ Hakaliah: Ní oṣù Kisleu ní ogún ọdún (ìjọba Ahaswerusi ọba Persia) nígbà tí mo wà ní ààfin Susa, Viz kapitolaYoruba Bible1 Ìtàn Nehemaya ọmọ Hakalaya. Ní oṣù Kisilefi, ní ogún ọdún tí Atasasesi jọba ní ilẹ̀ Pasia, mo wà ní Susa tíí ṣe olú-ìlú ilẹ̀ náà, Viz kapitolaBibeli Mimọ1 Ọ̀RỌ Nehemiah ọmọ Hakaliah. O si ṣe ninu oṣu Kisleu, ni ogún ọdun, nigba tí mo wà ni Ṣuṣani ãfin. Viz kapitola |