Online Bible

- Reklamy -




Nahumu 1:5 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

5 Àwọn òkè ńlá wárìrì níwájú rẹ̀, àwọn òkè kéékèèkéé sì di yíyọ́, ilẹ̀ ayé sì jóná níwájú rẹ̀, àní ayé àti gbogbo àwọn tí ń gbé inú rẹ̀.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

5 Àwọn òkè ńláńlá mì tìtì níwájú rẹ̀, àwọn òkè kéékèèké sì yọ́. Ilẹ̀ di asán níwájú rẹ̀, ayé ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀ di òfo.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

5 Awọn oke-nla mì nitori rẹ̀, ati awọn oke kékèké di yiyọ́, ilẹ aiye si joná niwaju rẹ̀, ani aiye ati gbogbo awọn ti ngbe inu rẹ̀.

Viz kapitola kopírovat




Nahumu 1:5

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy