Luku 1:62 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní62 Wọ́n sì ṣe àpẹẹrẹ sí baba rẹ̀, bí ó ti ń fẹ́ kí a pè é. Viz kapitolaYoruba Bible62 Wọ́n wá ṣe àpẹẹrẹ sí baba rẹ̀ pé báwo ni ó fẹ́ kí á máa pe ọmọ náà. Viz kapitolaBibeli Mimọ62 Nwọn si ṣe apẹrẹ si baba rẹ̀, bi o ti nfẹ ki a pè e. Viz kapitola |