Luku 1:61 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní61 Wọ́n sì wí fún un pé, “Kò sí ọ̀kan nínú àwọn ará rẹ̀ tí à ń pè ní orúkọ yìí.” Viz kapitolaYoruba Bible61 Wọ́n sọ fún un pé, “Kò sí ẹnìkan ninu àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ tí ó ń jẹ́ orúkọ yìí.” Viz kapitolaBibeli Mimọ61 Nwọn si wi fun u pe, Kò si ọkan ninu awọn ará rẹ ti a npè li orukọ yi. Viz kapitola |