Kolose 1:19 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní19 Nítorí ìfẹ́ Ọlọ́run ni pé kí gbogbo ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ òun tìkára rẹ̀ lè máa gbé nínú rẹ̀. Viz kapitolaYoruba Bible19 Nítorí ó wu Ọlọrun pé kí ohun tí Ọlọrun tìkararẹ̀ jẹ́ máa gbé inú rẹ̀ lẹ́kùn-únrẹ́rẹ́. Viz kapitolaBibeli Mimọ19 Nitori didun inu Baba ni pe ki ẹkún gbogbo le mã gbé inu rẹ̀; Viz kapitola |