Online Bible

- Reklamy -




Kolose 1:15 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

15 Kristi ni àwòrán Ọlọ́run tí a kò le rí, àkọ́bí gbogbo ẹ̀dá.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

15 Eniyan kò lè rí Ọlọrun, ṣugbọn ọmọ yìí ni àwòrán rẹ̀, òun ni àkọ́bí ohun gbogbo tí a dá.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

15 Ẹniti iṣe aworan Ọlọrun ti a kò ri, akọbi gbogbo ẹda:

Viz kapitola kopírovat




Kolose 1:15

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy