Online Bible

- Reklamy -




Jona 1:11 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

11 Nígbà náà ni wọ́n wí fún un pé, “Kí ni kí àwa ó ṣe sí ọ kí Òkun lè dákẹ́ fún wa?” Nítorí Òkun ru, ó sì ja ẹ̀fúùfù líle.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

11 Wọ́n bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé: “Kí ni kí á ṣe sí ọ, kí ìjì omi òkun lè dáwọ́ dúró? Nítorí ìjì náà sá túbọ̀ ń le sí i ni.”

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

11 Nigbana ni nwọn wi fun u pe, Kini ki a ṣe si ọ, ki okun le dakẹ fun wa? nitori okun ru, o si jà ẹfufu lile.

Viz kapitola kopírovat




Jona 1:11

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy