Johanu 1:4 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní4 Nínú rẹ̀ ni ìyè wà, ìyè yìí náà sì ni ìmọ́lẹ̀ aráyé, Viz kapitolaYoruba Bible4 Òun ni orísun ìyè, ìyè náà ni ìmọ́lẹ̀ aráyé. Viz kapitolaBibeli Mimọ4 Ninu rẹ̀ ni ìye wà; ìye na si ni imọlẹ̀ araiye. Viz kapitola |