Online Bible

- Reklamy -




Joẹli 1:6 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

6 Nítorí orílẹ̀-èdè kan ti ṣígun sí ilẹ̀ mìíràn ó ní agbára púpọ̀, kò sì ní òǹkà; ó ní eyín kìnnìún ó sì ní èrìgì abo kìnnìún.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

6 Orílẹ̀-èdè kan ti dojú kọ ilẹ̀ mi, wọ́n lágbára, wọ́n pọ̀, wọn kò sì lóǹkà; eyín wọn dàbí ti kinniun. Ọ̀gàn wọn sì dàbí ti abo kinniun.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

6 Nitori orilẹ-ède kan goke wá si ilẹ mi, o li agbara, kò si ni iye, ehin ẹniti iṣe ehin kiniun, o si ni erìgi abo kiniun.

Viz kapitola kopírovat




Joẹli 1:6

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy