Online Bible

- Reklamy -




Joẹli 1:18 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

18 Àwọn ẹranko tí ń kérora tó! Àwọn agbo ẹran dààmú, nítorí tí wọ́n kò ni pápá oko; nítòótọ́, àwọn agbo àgùntàn jìyà.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

18 Àwọn ẹran ọ̀sìn ń kérora, àwọn agbo mààlúù dààmú, nítorí pé kò sí pápá oko fún wọn; àwọn agbo aguntan pàápàá dààmú.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

18 Awọn ẹranko ti nkerora to! awọn agbo-ẹran dãmu, nitoriti nwọn kò ni papa oko; nitõtọ, a sọ awọn agbo agùtan di ahoro.

Viz kapitola kopírovat




Joẹli 1:18

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy