Online Bible

- Reklamy -




Joẹli 1:17 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

17 Irúgbìn bàjẹ́ nínú ebè wọn, a sọ àká di ahoro, a wó àká palẹ̀; nítorí tí a mú ọkà rọ.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

17 Irúgbìn díbàjẹ́ sinu ebè, àwọn ilé ìṣúra ti di ahoro, àwọn àká ti wó lulẹ̀, nítorí kò sí ọkà láti kó sinu wọn mọ́.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

17 Irugbìn bajẹ ninu ebè wọn, a sọ aká di ahoro, a wó abà palẹ; nitoriti a mu ọ̀ka rọ.

Viz kapitola kopírovat




Joẹli 1:17

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy