Jeremiah 1:8 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní8 Olúwa sì wí pé má ṣe bẹ̀rù wọn, nítorí tí èmi wà pẹ̀lú rẹ èmi ó sì gbà ọ́. Viz kapitolaYoruba Bible8 Má bẹ̀rù wọn, nítorí mo wà pẹlu rẹ, n óo sì gbà ọ́.” Viz kapitolaBibeli Mimọ8 Má bẹ̀ru niwaju wọn nitori emi wà pẹlu rẹ lati gbà ọ: li Oluwa wi. Viz kapitola |