Online Bible

- Reklamy -




Jeremiah 1:5 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

5 Kí ó tó di pé mo dá ọ láti inú ni mo ti mọ̀ ọ́n, kí ó sì tó di pé a bí ọ ni mo ti yà ọ́ sọ́tọ̀. Mo yàn ọ́ gẹ́gẹ́ bí wòlíì fún àwọn orílẹ̀-èdè.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

5 “Kí n tó dá ọ sinu ìyá rẹ ni mo ti mọ̀ ọ́, kí wọ́n sì tó bí ọ ni mo ti yà ọ́ sọ́tọ̀, mo yàn ọ́ ní wolii fún àwọn orílẹ̀-èdè.”

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

5 Ki emi ki o to dá ọ ni inu, emi ti mọ̀ ọ, ki iwọ ki o si to ti inu jade wá li emi ti sọ ọ di mimọ́, emi si yà ọ sọtọ lati jẹ́ woli fun awọn orilẹ-ède.

Viz kapitola kopírovat




Jeremiah 1:5

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy