Online Bible

- Reklamy -




Jeremiah 1:14 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

14 Olúwa, sì wí fún mi pé, “Láti apá àríwá ni a ó ti mu ìdààmú wá sórí gbogbo àwọn tí ó ń gbé ní ilẹ̀ náà.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

14 OLUWA bá sọ fún mi pé, “Láti ìhà àríwá ni ibi yóo ti dé bá gbogbo àwọn tí wọn ń gbé ilẹ̀ náà.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

14 Nigbana ni Oluwa sọ fun mi pe, ibi yio tú jade lati ariwa wá, sori gbogbo awọn ti ngbe inu ilẹ.

Viz kapitola kopírovat




Jeremiah 1:14

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy