Online Bible

- Reklamy -




Jeremiah 1:1 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

1 Èyí ni ọ̀rọ̀ Jeremiah ọmọ Hilkiah ọ̀kan nínú àwọn àlùfáà ní Anatoti ní agbègbè ilẹ̀ Benjamini.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

1 Ọ̀rọ̀ Jeremaya, ọmọ Hilikaya, ọ̀kan ninu àwọn alufaa tí ó wà ní Anatoti, ní ilẹ̀ Bẹnjamini nìyí.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

1 Ọ̀RỌ Jeremiah, ọmọ Hilkiah, ọkan ninu awọn alufa ti o wà ni Anatoti, ni ilẹ Benjamini.

Viz kapitola kopírovat




Jeremiah 1:1

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy