Isaiah 1:9 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní9 Àyàfi bí Olúwa àwọn ọmọ-ogun bá ṣẹ́ díẹ̀ kù fún wà, a ò bá ti rí bí Sodomu, a ò bá sì ti dàbí Gomorra. Viz kapitolaYoruba Bible9 Bí kò bá ṣe pé OLUWA àwọn ọmọ ogun dá díẹ̀ sí ninu wa ni, à bá rí bí i Sodomu, à bá sì dàbí Gomora. Viz kapitolaBibeli Mimọ9 Bikòṣe bi Oluwa awọn ọmọ-ogun ti fi iyokù diẹ kiun silẹ fun wa, awa iba ti dabi Sodomu, awa iba si ti dabi Gomorra. Viz kapitola |