Isaiah 1:31 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní31 Alágbára ọkùnrin náà yóò sì dàbí ohun ìdáná, iṣẹ́ rẹ̀ bí ẹ̀ṣẹ́-iná, àwọn méjèèjì ni yóò jóná papọ̀, láìsí ẹni tí yóò lè pa iná yìí.” Viz kapitolaYoruba Bible31 Alágbára yóo dàbí ògùṣọ̀, iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ bí ìṣáná. Àwọn mejeeji ni yóo jóná pọ̀, kò sì ní sí ẹni tí yóo lè pa iná náà. Viz kapitolaBibeli Mimọ31 Alagbara yio si dabi ògùṣọ̀, iṣẹ rẹ̀ yio si dabi ẹta-iná, ati awọn mejeji yio jọ jona pọ̀, ẹnikẹni kì yio si pa wọn. Viz kapitola |