Online Bible

- Reklamy -




Isaiah 1:29 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

29 “Ojú yóò tì yín nítorí igi óákù mímọ́ èyí tí ẹ ní inú dídùn sí, a ó kàn yín lábùkù nítorí àwọn ọgbà yìí tí ẹ ti yàn fúnrayín.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

29 Ojú yóo tì yín, fún àwọn igi Oaku tí ẹ nífẹ̀ẹ́ láti máa bọ. Ojú yóo sì tì yín fún àwọn ọgbà oriṣa tí ẹ yàn.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

29 Nitoriti oju yio tì wọn niti igi-nla ti ẹnyin ti fẹ, a o si dãmu nyin niti ọgbà ti ẹnyin ti yàn.

Viz kapitola kopírovat




Isaiah 1:29

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy