Isaiah 1:28 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní28 Ṣùgbọ́n àwọn ọlọ̀tẹ̀ àti àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ni a ó parun. Àwọn tí ó bá sì kọ Olúwa sílẹ̀ ni yóò ṣègbé. Viz kapitolaYoruba Bible28 Ṣugbọn a óo pa àwọn ọlọ̀tẹ̀ ati àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ run, àwọn tí ó kọ OLUWA sílẹ̀ yóo sì ṣègbé. Viz kapitolaBibeli Mimọ28 Iparun awọn alarekọja pẹlu awọn ẹlẹṣẹ yio wà pọ̀, ati awọn ti o kọ̀ Oluwa silẹ li a o parun. Viz kapitola |