Online Bible

- Reklamy -




Isaiah 1:26 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

26 Èmi yóò mú àwọn adájọ́ rẹ bọ̀ sí ipò gẹ́gẹ́ bí i ti àtijọ́, àti àwọn olùdámọ̀ràn rẹ̀ bí i ti ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀. Lẹ́yìn náà ni a ó pè ọ ní ìlú òdodo, ìlú òtítọ́.”

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

26 N óo dá àwọn onídàájọ́ rẹ pada sí ipò tí wọn ti wà tẹ́lẹ̀. Ati àwọn olùdámọ̀ràn rẹ, lẹ́yìn náà a óo máa pè ọ́ ní ìlú olódodo.”

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

26 Emi o si mu awọn onidajọ rẹ pada bi igbà iṣãju, ati awọn igbìmọ rẹ bi igbà akọbẹ̀rẹ: lẹhin na, a o pè ọ ni, Ilu ododo, ilu otitọ.

Viz kapitola kopírovat




Isaiah 1:26

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy