Online Bible

- Reklamy -




Isaiah 1:23 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

23 Ọlọ̀tẹ̀ ni àwọn aláṣẹ yín, akẹgbẹ́ àwọn olè, gbogbo wọn ló fẹ́ràn àbẹ̀tẹ́lẹ̀ wọ́n sì ń wá ẹ̀bùn kiri. Wọ́n kì í ṣàtìlẹyìn fún ẹ̀tọ́ aláìní baba, ẹjọ́ opó kì í sì í dé iwájú wọn.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

23 Ọlọ̀tẹ̀ ni àwọn ìjòyè rẹ, ati ẹgbẹ́ olè; gbogbo wọn ni wọ́n fẹ́ràn àbẹ̀tẹ́lẹ̀, tí wọn sì ń wá ẹ̀bùn káàkiri. Wọn kì í gbèjà aláìníbaba, bẹ́ẹ̀ ni wọn kì í gba ẹjọ́ opó rò.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

23 Awọn ọmọ-alade rẹ di ọlọ̀tẹ, ati ẹgbẹ olè: olukuluku nfẹ́ ọrẹ, o si ntọ̀ erè lẹhin: nwọn kò ṣe idajọ alainibaba, bẹ̃ni ọ̀ran opó kò wá sọdọ wọn.

Viz kapitola kopírovat




Isaiah 1:23

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy