Online Bible

- Reklamy -




Isaiah 1:17 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

17 kọ́ láti ṣe rere! Wá ìdájọ́ òtítọ́, tu àwọn tí a ń pọ́n lójú nínú. Ṣàtìlẹyìn fún ẹ̀tọ́ aláìní baba, gbà ẹjọ́ opó rò.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

17 Ẹ lọ kọ́ bí eniyan tí ń ṣe rere. Ẹ máa ṣe ẹ̀tọ́. Ẹ máa ran ẹni tí ara ń ni lọ́wọ́. Ẹ máa gbìjà aláìníbaba, kí ẹ sì máa gba ẹjọ́ opó rò.”

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

17 Kọ́ lati ṣe rere; wá idajọ, ràn awọn ẹniti a nilara lọwọ, ṣe idajọ alainibaba, gbà ẹjọ opó rò.

Viz kapitola kopírovat




Isaiah 1:17

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy