Isaiah 1:12 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní12 Nígbà tí ẹ wá farahàn níwájú mi, ta ni ó béèrè èyí lọ́wọ́ yín, Gìrì gìrì ẹsẹ̀ nínú àgbàlá mi? Viz kapitolaYoruba Bible12 Nígbà tí ẹ bá wá jọ́sìn níwájú mi, ta ló bẹ̀ yín ní gbogbo gìrìgìrì lásán, tí ẹ̀ ń dà ninu àgbàlá mi. Viz kapitolaBibeli Mimọ12 Nigbati ẹnyin wá lati fi ara hàn niwaju mi, tali o bere eyi lọwọ nyin, lati tẹ̀ agbalá mi? Viz kapitola |