Online Bible

- Reklamy -




Heberu 1:6 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

6 Àti pẹ̀lú, nígbà tí Ọlọ́run rán àkọ́bí rẹ̀ wá si ayé wa yìí. Ó pàṣẹ pé, “Ẹ jẹ́ kí gbogbo àwọn angẹli Ọlọ́run foríbalẹ̀ fún un.”

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

6 Ṣugbọn nígbà tí ó mú àkọ́bí rẹ̀ wọ inú ayé, ohun tí ó sọ ni pé, “Kí gbogbo àwọn angẹli Ọlọrun foríbalẹ̀ fún un.”

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

6 Ati pẹlu, nigbati o mu akọbi ni wá si aiye, o wipe, Ki gbogbo awọn angẹli Ọlọrun ki o foribalẹ fun u.

Viz kapitola kopírovat




Heberu 1:6

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy