Online Bible

- Reklamy -




Heberu 1:12 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

12 Ní kíká ni ìwọ yóò ká wọn bí aṣọ, bí ìpààrọ̀ aṣọ ni a ó sì pààrọ̀ wọn. Ṣùgbọ́n ìwọ fúnrarẹ̀ kì yóò yípadà àti pé ọdún rẹ kì yóò ní òpin.”

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

12 Gẹ́gẹ́ bí eniyan tií ká aṣọ ni ìwọ óo ká wọn. Gẹ́gẹ́ bí aṣọ, a óo pààrọ̀ wọn. Ṣugbọn ní tìrẹ, bákan náà ni o wà. Kò sí òpin sí iye ọdún rẹ.”

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

12 Ati bi aṣọ ni iwọ o si ká wọn, a o si pàrọ wọn: ṣugbọn bakanna ni iwọ, ọdún rẹ kì yio si pin.

Viz kapitola kopírovat




Heberu 1:12

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy