Online Bible

- Reklamy -




Heberu 1:11 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

11 Wọn yóò ṣègbé, ṣùgbọ́n ìwọ yóò wà síbẹ̀ gbogbo wọn ni yóò di àkísà bí ẹ̀wù.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

11 Wọn óo parẹ́ ṣugbọn ìwọ óo wà títí. Gbogbo wọn óo gbó bí aṣọ.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

11 Nwọn ó ṣegbe; ṣugbọn iwọ ó wà sibẹ, gbogbo wọn ni yio si gbó bi ẹwu;

Viz kapitola kopírovat




Heberu 1:11

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy