Online Bible

- Reklamy -




Hagai 1:4 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

4 “Ǹjẹ́ àkókò ni fún ẹ̀yin fúnrayín láti máa gbé ní ilé tí a ṣe ní ọ̀ṣọ́ nígbà tí ilé yìí wà ni ahoro?”

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

4 “Ẹ̀yin eniyan mi, ṣé àkókò nìyí láti máa gbé inú ilé tiyín tí ẹ ṣe lọ́ṣọ̀ọ́, nígbà tí Tẹmpili wà ní àlàpà?

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

4 Akokò ha ni fun nyin, ẹnyin, lati ma gbe ile ọṣọ nyin, ṣugbọn ile yi wà li ahoro?

Viz kapitola kopírovat




Hagai 1:4

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy