Online Bible

- Reklamy -




Hagai 1:2 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

2 Báyìí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí: “Àwọn ènìyàn wọ̀nyí wí pé, ‘Kò tí ì tó àkókò láti kọ́ ilé Olúwa.’ ”

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

2 OLUWA àwọn ọmọ ogun ní: “Àwọn eniyan wọnyi ní, kò tíì tó àkókò láti tún Tẹmpili kọ́.”

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

2 Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi, Awọn enia wọnyi nsọ pe, Akokò kò ti ide, akokò ti a ba fi kọ́ ile Oluwa.

Viz kapitola kopírovat




Hagai 1:2

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy