Online Bible

- Reklamy -




Gẹnẹsisi 1:31 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

31 Ọlọ́run sì rí àwọn ohun gbogbo tí ó dá, ó dára gidigidi. Àṣálẹ́ àti òwúrọ̀, ó jẹ́ ọjọ́ kẹfà.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

31 Ọlọrun wo gbogbo ohun tí ó dá, ó sì rí i pé wọ́n dára. Ilẹ̀ ṣú, ilẹ̀ sì tún mọ́, ó di ọjọ́ kẹfa.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

31 Ọlọrun si ri ohun gbogbo ti o dá, si kiyesi i, daradara ni. Ati aṣalẹ ati owurọ̀ o di ọjọ́ kẹfa.

Viz kapitola kopírovat




Gẹnẹsisi 1:31

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy