Online Bible

- Reklamy -




Gẹnẹsisi 1:27 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

27 Nítorí náà, Ọlọ́run dá ènìyàn ní àwòrán ara rẹ̀, ní àwòrán Ọlọ́run ni Ó dá a, akọ àti abo ni Ó dá wọn.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

27 Bẹ́ẹ̀ ni Ọlọrun dá eniyan ní àwòrán ara rẹ̀. Takọ-tabo ni ó dá wọn.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

27 Bẹ̃li Ọlọrun dá enia li aworan rẹ̀, li aworan Ọlọrun li o dá a; ati akọ ati abo li o dá wọn.

Viz kapitola kopírovat




Gẹnẹsisi 1:27

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy