Filipi 1:5 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní5 nítorí ìdàpọ̀ yín nínú ìhìnrere láti ọjọ́ kìn-ín-ní wá títí di ìsinsin yìí. Viz kapitolaYoruba Bible5 Nítorí láti ìbẹ̀rẹ̀ títí di àkókò yìí ni ẹ ti ń bá mi ṣiṣẹ́ pọ̀ ninu iṣẹ́ ìyìn rere. Viz kapitolaBibeli Mimọ5 Nitori ìdapọ nyin ninu ihinrere lati ọjọ kini wá titi fi di isisiyi. Viz kapitola |