Online Bible

- Reklamy -




Filipi 1:30 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

30 Ẹ sì máa ja ìjà kan náà, èyí ti ẹ̀yin ti ri, ti ẹ sì ti gbọ́ pé èmi n jà pẹ̀lú.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

30 Irú ìyà kan náà tí ẹ rí ninu ìgbé-ayé mi, tí ẹ tún ń gbọ́ pé mò ń jẹ títí di àkókò yìí ni ẹ̀yin náà ń jẹ báyìí.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

30 Ẹ si ni ìja kanna ti ẹnyin ti ri ninu mi, ti ẹnyin si gbọ́ nisisiyi pe o wà ninu mi.

Viz kapitola kopírovat




Filipi 1:30

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy