Online Bible

- Reklamy -




Filipi 1:29 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

29 Nítorí tí a ti fún yin ni àǹfààní, kì í ṣe láti gba Kristi gbọ́ nìkan, ṣùgbọ́n láti jìyà nítorí rẹ̀ pẹ̀lú:

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

29 Nítorí anfaani ni èyí fun yín, kì í ṣe pé kí ẹ gba Kristi gbọ́ nìkan ni, ṣugbọn pé ẹ̀ ń jìyà fún Kristi.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

29 Nitori niti Kristi, ẹnyin li a ti yọnda fun, kì iṣe lati gbà a gbọ́ nikan, ṣugbọn lati jìya nitori rẹ̀ pẹlu:

Viz kapitola kopírovat




Filipi 1:29

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy