Online Bible

- Reklamy -




Filipi 1:23 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

23 Ṣùgbọ́n èmi n ṣiyèméjì, nítorí ti èmi fẹ́ láti lọ kúrò nínú ayé yìí, láti wà lọ́dọ̀ Kristi; nítorí ó dára púpọ̀ jù:

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

23 Ọkàn mi ń ṣe meji; ọkàn mi kan fẹ́ pé kí á dá mi sílẹ̀, kí n lọ sọ́dọ̀ Jesu, nítorí èyí ni ó dára jùlọ.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

23 Ṣugbọn emi mbẹ ni iyemeji, mo ni ifẹ lati lọ ati lati wà lọdọ Kristi; nitori o dara pupọ ju:

Viz kapitola kopírovat




Filipi 1:23

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy