Online Bible

- Reklamy -




Filemoni 1:5 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

5 nítorí mo ń gbọ́ nípa ìgbàgbọ́ rẹ nínú Jesu Olúwa àti nípa ìfẹ́ rẹ sí àwọn ènìyàn mímọ́.

Viz kapitola kopírovat

Yoruba Bible

5 Mò ń gbọ́ ìròyìn ìfẹ́ ati igbagbọ tí o ní sí Oluwa Jesu, ati sí gbogbo àwọn onigbagbọ.

Viz kapitola kopírovat

Bibeli Mimọ

5 Bi mo ti ngbọ́ ti ifẹ rẹ ati igbagbọ́ ti iwọ ni si Jesu Oluwa, ati si gbogbo awọn enia mimọ́;

Viz kapitola kopírovat




Filemoni 1:5

Následuj nás:

Reklamy


Reklamy